1 Òkan nínú àwon ángẹ́lì méje tíó ńgbé ọ̀gbón méje nìì lówó tòmí wáá, ósì wífún mi pé; "Wá èmi yíò se àfihàn ìdálẹ́bi alágbèrè ńlá nìì tíó jòkó lórí omi púpò, 2 ẹni tí àwọn ọba ayé báse àgbèrè, àti ọtí àgbèrè ni gbgbo àwon olùgbé ayé ti mu yó 3 Nígbà náà ni ángẹ́lì yìí gbé mi lọ nínú Ẹmí sí asálè kan, mosì rí obìrin kan tíó jókòó lóríi ẹranko pupa kan tí ó kún fún àwọn orúko ìsòròòdì síí kún ararẹ̀. Ẹranko yìí níí orí méje àti ìwo mẹ́wàá 4 Obìrin náà wọ asọ àlárì àti asọ pupa tí wọ́n fi wúrà, òkúta iyebíye àti ìlèkè se lọ́sọ̀ọ́. Obìrin na mú ife wúrà tíí ókún fún ohun ẹlẹ́gbin àti ohun àìmọ́ àgbèrẹ̀ rẹẹ̀ 5 Wọ́n kọ orúkọ tíí óní ìtum̀ ìkòkò: Bábílónì ńlá, ìyá àwọn onínàbì àti àwọn ohun ẹlẹ́gbin ayé yìí. 6 Morí obìrin náà tí ó ti yó fún àmupara ẹ̀jẹ àwọn ènìyàn mímọ́ Ọlọ́run àti àwọn tí wọ́n kú nítori ìgbàgbọ́ nínú Jésù. Nígbàtí mo ríi, ẹnú yà mí gidigidi 7 Sùgbọ́n ángẹ́lì náà wífún mi pé, "èèsée tí ẹnu yà ọ́?" Èmi yíò sàlàyé obìrin náà, àti eranko tí ó gbe, àti ẹranko tí ó níí orí méje àti ìwo mẹ́wàá. 8 Ẹranko tí ìwọ́ rí yìí ti wàláyé ní gbàkan rí, kò ṣíláyé mọ́ nísìsìyí, ósìti múra tán láti jáde wá láti inú ọ̀gbun jínjìn. Yíò sì párun, àwọn tó ńgbé ilé ayé tí akó kọ orúkọ wọn sínú ìwé ìyè láti ìpilẹ̀sẹ̀ ayé- ẹnu yíò sì yà wọ́n nígbàtí wọ́n bá rí ẹranko náà nítorí ótiwà nígbàkan rí, kò sì ṣí mó, ósìtún bò. 9 èyí pèfún ọkàn tíó ní ọgbón, orí méje ni orí òkè méje tí obìrin náà jókò lé 10 ọba mèje ni wọ́ pẹ̀lú. Ọba màrùń ti subú, ọ̀kan sìì wà, ọ̀kan tókù kòtí wàá, nígbà tíó bádé, ósì gbọdọ̀ wà fún ìgbà díè. 11 Ẹranko tí ó wà tẹ́lẹ̀, ṣùgbọ́n kò sì nísinsìnyí, òhun fuńrarẹ̀ ni ọba kẹjọ; sùgbọ́n ó jẹ́ ọ̀kán nínú àwọn ọba méje wọ̀n ọn nì, àti pé ó ńlọ sí ìparun. 12 Àwọn ìwo mẹ̀wàá náà tí o rí ni àwọn ọba mẹ́wàá tí wọn kò tíì gba ìjọba, ṣùgbọ́n wọn yóò gba àṣẹ gẹ́gẹ́ bí ọba fún wákàtí kan pẹ̀lù ẹranko. 13 Àwọn wọ̀nyí wà ní ìṣọ̀kán, wọ́n sì fi agbára àti àṣẹ wọn fún ẹranko náà. 14 Wọn á gbógun ti ọ̀dọ́ Àgùntan. Sùgbọ́n ọ̀dọ́ Àgùntàn náà yóò ṣẹ́gun wọn nìtorí òun ni Olúwa àwọn olúwa àti Ọba àwọn ọba- pẹ̀lú rẹ̀ ni àwọn tí a pè, àwọn tí a yàn, ati àwọn olóòtọ́." 16 Àwọn ìwo mẹ́wáá náà tí ìwọ rí - àwọn àti ẹranko náà yóo kóríra aṣẹ́wó náà. Wọ́n yóò sọọ́ di ahoro àti ìhòhò, wọn yóò jẹ ẹran ara rẹ̀, àti wípé wọn yóò sun-ún patapata pẹ̀lù iná. 17 Nítorí Olọ́run ti fi sí wọn lọ́kàn làti mú ète rẹ̀ ṣẹ nípa ìfẹnu kò láti fi agbára ìjọba wọn fún ẹranko náà títí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run yóò fi wá sí ìmúsẹ. 18 obirin ti ori ni ni ilu nla ni ti ondari awon ọba aye