1 T osi ya ni aya ka fu ara balẹ fu asaju ya wu alasẹ yan, aya ka gbo fu ya ni aya ka mura fu iwa ire ya kise. 2 Tosi ya ni aya ka ma fọ afọ onikan l'eseku, ni aya ka ma gla ijiyan ya, l'ayé; ni aya ka nu kidou fu enin kemin bẹẹni, aya ka fu ki re ara nẹ silẹ han su onia gudugudu. 3 Ndi ni awa gbo ngba kan wa lọ yi aye enin ka fu nkape wu ẹnin ka gbayen ẹ. Ara wa lọ nov onon isekise wu ayé ijẹkijẹ. Agbé wa lo n'non iseku wu oju kunkun.a s'egbin l'oju onia ya nin a binon ara wa. 4 Ama, ye oju iré olorun olugba la wa wu ifẹ fu oma ya fara han ẹ. 5 Ogba wa la , kore ndi ṅi ase iwa otitoọ kan, ama gede ndi aanon ẹ ni. Ogba wala gla nta wẹmi wa wu ki sọ di alaye titun- n'non Emi kima 6 Olọhun tu Emimon kipo si si l'ara wa gba nta Jésu-Kristi oligbagba wa. 7 Ose bẹ ndi ni lẹé ni aya sowạ di olotitọ ẹ l'epa ore ofẹ ẹ,ka di ajogu igbagbọ ayé ainẹ ipeku. 8 Aifo ye yẹ ki gbẹ kanle. Ma wo ni iwa fo afo ye ya dagadaju ndi ni Enin ye gla oloan glo ya ẹaya ka gla ni aya fu iwa ise iré ki se ye olonu fu ya. Nran ye ya sian ni oyẹ ona oria ya 9 ka fu ijian gbada, wu itàn abimibi ya wu ijà koyẹ aya sin jẹ ogbooro ni. 10 Enin ye a da ipin si limeji yẹ, kila fu alẹkénénn bi ko mi, kilo fu alekegi, bi ko parọ ni sa fu. 11 Ka ma ni ẹnẹn bẹ ti fu aṅi di ona gaga ni owa a sẹ ni a jẹbi fara ẹ. 12 N'gba ma nẹ Artenasi ni bi Tissiki wa, ya ara wa ba mi n'Nicopolis nbẹ ni ma wa a. 13 Ya ara nẹ Zénas olofi wu Appolo wa fu mi ndi nkakan koma di bo fu ya 14 Owa ni Enẹ wa yạ kạ kọ isẹ ire kise ni ka ji fu na ju nka ye a wa ba l'ojiji ya ẹ, ni ka ma wa lassẹ. 15 Emi enin mo wa ya gudugudu aya ki.ki enin fa wa yan n'non igbagbọ ya ẹ ore ofẹ ko wa wu yẹ.