1

3 Kí Ọlọ́run àti baba Kristi Jesù Olúwa wa di yínyín lógo, ẹni tí o fi ìbùkún gbogbo fún wa nínú Jésù ní inú àwọn ọ̀run. 4 Ọlọ́run ti yàn wá nínú rẹ̀ láti ìpilẹ̀sẹ̀ ayé , pé kí a le jẹ́ mímọ́ àti aìléèrí lójú rẹ̀ nínú ìfẹ́.