orí kéjè

3 ohún ní alíàní Bàbá ,alíàní iya ,aláìní ní ibẹrẹ ojo bẹní opin aye rẹ́ . dipo, o jo ọmo Ọlọ́run,Nítorí o je álúfáà titi lia. 1 Mẹ̀dísédékì yí,Ọba sáàlem, Álúfáà Ọlọ́run to ja júlò,ẹni tí o pádè ábráhàmù to ń bọ́ látì ibi tí o tí sẹ́gun àwon ọba ó sì búkùn . 2 Ohún ní ẹni tí ábràhùmù fún ní ìdámẹ̀wá ohún gbogbo. Orúko rẹ̀ ní ``mẹ̀dísédékì ´´tumo si ´´ Ọba olódodo. ´´ ohún na ní ``Ọba sáàlem,´´ tí o tumo sí ``Ọba aláàfiá.´´ 4 E rí bi ókùnrin yi se ga to , Bàbá wa ábráhàmù fun kẹwa àwon ńǹkan ti o tí mú lójù ogún. 5 Ní ona mìíran, àwon ọmo lefi tí o gbá sẹ àlùfáà ní ase kan látì inu ofin látì gba ìdámẹ̀wá lówó àwon ènìyàn,Ẹyi ní wípè látì owo àwon arakunrin wón, Biotile je pé àwon pélù wa látì inu ara ábráhàmù. 6 Ṣùgbón ní ọ̀nà míìran, Mẹ̀dísédékì, Ẹnití kò tí inú ìran wọn wá, Ó gba ìdámèwá lówó ábráhámù , ó se ibùkún fún-ùn, ẹnití ó ní àwon ìlérí. 11 Tí ìsonìdìpípé bá seése nípa àwon àlùfáà lefítíkù nísinsìnyí (nítorí iábé won ní àwon ènìyàn ti gba òfin), kí wá tún ni ìdíi rẹ̀ fún àlùfáà míràn láti dìde ní bíi ti ẹ̀yá mẹ̀dísédékè láìsì jẹ bi tí èyà ti Áarónì? 12 Nítorí tí a bá pààrọ̀ àlùfáà, a gbọdọ̀ pàrọ̀ ọ̀ òfin náà. 13 Nitóri enití à ń sọ àwon ńǹkan wọ̀nyí nípa rẹ̀ je ẹ̀yà míìràn, Fún enití ko tí sesẹ́ oríi pẹpẹ rí. 14 Ódájú nísinsìnyí pé ìran júdà ni a bi Ọlúwa