1 N'dibe olufẹ mi ya, uwu ẹnin mi ya, ẹ yẹ ye ẹjẹ ayọ mi uwu ade mi, ẹf'ẹsẹ mulẹ bẹ n'non ọluwa, olufẹ mi ya. 2 Man gba Erodie liyanju uwu sintike ni aya ka nin ọkan kan n'non oluwa. 3 Wogbo n'ja mi otitọ man bẹ ni iran ya lọwọ obon in ye ya bami ja ija iroyi ayọ, fu man klemen uwu ala jẹ sè isẹ pọ mi ọmonin ya gbo ékọ ya tiwa lọsọ iwe iyé ẹ. 4 Ẹẹ yọ n'non oluwa lasiko kasiko mo tese a fọọ, ẹẹ yọ. 5 Kidon yẹ ko di kiman fu onian gudu gudu, oluwa tifẹ dè. 6 Ẹ mase kẹ da yanyan n'kankan, ama n'non n'kan gudu gudu, ẹfọ n'kan ye ẹ wo ẹfu ọlọon lẹpasẹ adua, ẹbẹ adua uwu idupẹ. 7 Ni alafia ọlọon, ye kọja ọgban gudu gudu ẹ n'kọpa ọkan yẹ uwu isẹẹ yẹ ya man n'nan Jesu Kristi. 8 Ẹnin mi ya ye bọẹ ni; n'kan gudu gudu ye jẹ otitọ, n'kan gudu gudu ye yẹka bọlafu, n'kan gudu gudu ye wa gangan ẹ, n'kan gudu gudu ye jẹ kiman, n'kan gudu gudu ye yẹ ki fian, n'kan gudu gudu ye yẹ kafọ l'ire ẹ, ye sian gbo o ye fu iyi ẹ, un ni ọwa nikaa wa n'nan iséé yẹ ya. 9 N'kan ye ẹkon, gbo ẹ gba, gbo ẹ gbọ l'ara mi uwu ye ẹ ri n'di mi ẹ, e mu lo ni ọlọọn alafia kọ wa uwu yẹ 10 Mo ri ayọ lakun kan n'non oluwa, ye gbo etiko nin iro titon kan lọsọ ọkan yẹfu mi ẹ, iséé yẹ sian, ama ọnan ni ko si fu yẹ. 11 Kose n'di ainin mi ni man fọ bẹ n'dini emi mo ti kan inan kidan ki nin n'ta imanu ye wa lọwọmi ẹ. 12 Mọ man bẹnẹni onian a gbe n'non irẹlẹ, ni mọ man bẹnẹni onian a nin kipọ, n'nan n'kan gudu gudu, n'di gudu gudu mọ kon ki jẹ yo uwu kigbe l'ebi, ki nin kipọ uwu ki ma nin ifèfè. 13 Man tiko se n'kan gudu gudu lẹpa ẹnin ye a fu mi l'agbara ẹ. 14 Ama ẹ sèè kipọ n'di ye ẹ kẹ jọ n'ki emi ni kan so n'non ibanonjẹ mi. 15 Ẹyẹ pa-paa ọma ilu, Filipu ya ẹ man, ye iroyi ayọ pe lajusin gbo mọ dide n'makeduani ẹ, ijon kan kọ ran mi l'ọwọ n'non ye an fu gbo angba ẹ. 16 Ẹyẹ géé ni ẹ tiko se iran l'ọwọ mi, n'dini n'gba ye mọ wa n'tesaloniki ẹ pa-paa ẹfu n'kan ya nin kọ wa fu mi, ni igbo meji ọtọ ọtọ ni ẹ ninkọ wafu ainin mi. 17 Kose ni man wo ni kẹ wan fu mi, ama man wo isiso kipọ fu yẹ ni. 18 Mọ gba gudu gudu ẹ, ni mọ nin kipo, modi ọlọla n'gba ye mọ gba n'kan ye ya ẹ fu nẹ épafroditi fu mi ẹ gbo ọ nin ooun kidon benẹni ikunra ki runfin fin, ẹbọ kan ye ọlọon tẹwọ gba gbo ọ don fu ẹ. 19 Bẹni ọlọon mi n'ko pèséfu ainin yẹ gudu gudu n'non ọla lakun ẹ lọsọ ogo n'non Jesu Kristi. 20 Ni ogo kọ jẹ ti ọlọon, baba wa titi laè fu di laè laè. Aamin. 21 Ẹ ki onian minon n'non Jesu Kristi ya gudugudu ẹnin ye wa n'di t emi ya gbo an ki yẹ. 22 Onian ki man gudugudu ya ya a ki ye, papaa, enin ye wa lọsọ ile kesari ya ẹ. 23 Ore ọfẹ ẹ oluwa wa, Jesu Kristi kọ ba ẹmi ye gbé.